Loading Events

« All Events

  • This event has passed.

Pipin Aala Asa ati Alaafia Okan

April 28 @ 11:00 am - 12:00 pm

Darapọ mọ wa lati ni imọriri fun awọn aṣa miiran lakoko ti o wa ni asopọ si tiwa

Alaafia okan se pataki gegebi alafia ago ara wa, ni ilu to yato si orisun wa, a nilo lati mo bi ase le gbe asa ati igbagbo pelu ise lbi ti ati wa ati ibi ti a wa lori gbedeke. Akosemose oludaninimoran you tan imole si awon ona ti ale gba lati ma sonu sajo ati lati mo riri orisirisi asa to yi wa ka ati ona ti won ngba di wa lowo tabi ran wa lowo lati ni alaafi ati idunnu.

Venue

Toronto, Ontario
Toronto, CA + Google Map