
- This event has passed.
Itoju Akoko fun Alaafia Okan ati Opolo (Mental Health First Aid)
September 28, 2022 @ 12:00 pm - 1:00 pm

The mental health department at Skills for Change will be holding this session.
Yoruba Description: Ninu idanileko yii a hoo kọ ẹkọ pataki nipa Iranlọwọ akọkọ ti ọpọlọ, bawo ni a ṣe le funni ni iranlọwọ yi? Ohun ti a nilo lati se yoo da lori ipo ti awon to nilo itoju yi wa ni asiko naa. Iwọ yoo tun kọ ẹkọ awọn idi ati isepataki ti pipese iranlọwọ ni kiakia fun awọn eniyan ti o nilo iranlọwọ, lati yago fun awọn iṣoro ilera ọpọlọ, lati rii daju pe gbogbo eniyan ni agbegbe ni idaabobo to pe.
English Description: In this workshop we will be learning the importance of Mental Health First Aid, how we can offer help and what we need to do depending on individual situation and needs. You will also learn the basic objectives of providing prompt assistance to people who need help, in order to prevent complicated mental health problems and ensure safety of everyone in the community.
Contact info:
Titilola Omotosho
Tel: 416-658-3101 ext.239
Email: tomotosho@skillsforchange.org / mentalhealth@skillsforchange.org