Loading Events

« All Events

  • This event has passed.

Gigbogun ti Iberu ati Ifoya wa (Fighting Fear and Anxiety)

July 27, 2022 @ 12:00 pm - 1:00 pm

The mental health department at Skills for Change will be holding this session.

Opolopo eniyan lo un gbe pelu ifoya ati iberu paapaa julo bi a se n dojuko ijakale arun ati oniruru ogun ati ijamba kaakiri agbaye. Eleyi to le se okunfa arun opolo ati iku aitojo. Idanileko yi yoo fun wa ni fani ati ko bi a se lee gbe igbese lati doju ija ko iberu ati ifoya wa.

Contact info:
Titilola Omotosho
Tel: 416-658-3101 ext.239
Email: tomotosho@skillsforchange.org / mentalhealth@skillsforchange.org

Venue

Toronto, Ontario
Toronto, CA + Google Map